Eyi ni alaye Suratul Fatiha lati Aayah akoko titi de Aayah keta pelu awon eko l’oniranran.
Alaye ohun ti a n pe ni igberaga ohun naa ni ki eniyan maa se atako ododo ti o fi oju han ati yiyepere awon eniyan miran.
Oro nipa awon ohun ti a maa nyo Saka ninu won, ati oundiwon ti a o yo ninu awon nkan ti Saka wo, Olubanisoro si bere pelu Aayah Alukuraani ti o nso nipa ijiya ti nbe fun awon ti won maa nko dukia jo laiyo Saka ninu re.
Ibanisoro yii da lori sise alaye nkan ti o nje Oselu ati oniranran eya oselu ti awon eniyan nse pelu nkan ti Islam gbe wa gege bi Eto Oselu.
Eyi ni alaye awon Hadisi ti o n so nipa awon ojo ti Shari’ah ko fun Musulumi lati maa gba aawe ninu won ati awon eko esin ti o ro mo won.
1- Alaye ni ekunrere lori eto ise egbe alajeseku ni ilana ti Islam, ati alaye nipa aburu ti o nbe nibi owo-ele (Riba), eri re lati inu Alukuraani mimo ati Oro Ojise Olohun. 2-Alaye ni afikun lori awon okowo ti Islam gbe kale ti a le maa lo ninu egbe alajeseku gege bii: Musharakah, Mudarabah, Murabahah ati bee bee lo.
Idanileko yi je alaye lori hadiisi eleekeje ninu tira “Umdatul Ahkaam”, koko oro idanileko naa ni alaye nipa bi ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o o maa ba a- se maa nse aluwala.
Oro lori bi Annabi- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- se ko awon Sahabe re ni eko ti aye won fi dara ti orun won naa si rorun.
Eyi ni alaye oro lekunrere nipa asigbo ati ero buburu ti awon eniyan ni si awon musulumi ati Esin Islam, ti olubanisoro si tun se alaye awon iruju die nipa iko “Boko Haram”.
Olubanisoro se alaye awon eto oro-aje agbaye ti o denukole, awon okunfa won ati awon ona abayo ti Islam gbe kale fun awon isoro yii.
Idanileko yi so nipa awon idajo esin ti o ro mo irun pipe, oniwaasi so oro nipa re ni ifosiwewe nigbati o nse alaye awon hadiisi ti o ro mo o.
Eleyi ni itumo awon hadiisi kan ti o so nipa sakaatul fitri ti awon Yoruba npe ni jaka. Oniwaasi se alaye awon idajo esin ti o ro mo o gege bii awon ti o ye ki o yo o, irufe ounje ti a fi maa nyo o ati odiwon ti o ye ki a yo.
Idanileko yi so nipa awon eko ti Islam gbe kale fun eniti o ba ngba aawe gege bii yiyara fun isinu ati lilora lati je saari, bakannaa ni oludanileko tun so oro nipa asiko ti aawe maa nbere ati asiko ti o maa npari, o si tun so nipa bi esin Islam se se aawe agbayipo ni eewo.
Itumo IgberagaBy Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
Alaye Suratul Fatiha - 1By Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
Alaye Suratul Fatiha - 2By Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
E
Egbe Alajeseku Ninu Islam (Islamic Co-Operative)


1
Egbe Alajeseku Ninu Islam (Islamic Co-Operative) - 1
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Egbe Alajeseku Ninu Islam (Islamic Co-Operative) - 1By Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
E
Egbe Alajeseku Ninu Islam (Islamic Co-Operative)


1
Egbe Alajeseku Ninu Islam (Islamic Co-Operative) - 2
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Egbe Alajeseku Ninu Islam (Islamic Co-Operative) - 2By Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
B
Bi Ojise Olohun ti ko Awon Saabe re ni Eko


1
Bi Ojise Olohun ti ko Awon Saabe re ni Eko
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Bi Ojise Olohun ti ko Awon Saabe re ni EkoBy Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
Yiyo SakaBy Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
Idajo Esin Lori Gbigba Aawe ni Ojo JimohBy Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
E
Eto Oro-aje Agbaye ti o d’enukole ati Ona Abayo ti Islam gbe kale


1
Eto Oro-aje Agbaye ti o d’enukole ati Ona Abayo ti Islam gbe kale
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Eto Oro-aje Agbaye ti o d’enukole ati Ona Abayo ti Islam gbe kaleBy Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
Idahun si Awon Iruju Kan nipa Esin IslamBy Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
A
Alaye lori Awon Hadiisi ti o so nipa Gbigba Aawe ni ori Irinajo ninu tira Umdatul Ahkaam


1
Alaye lori Awon Hadiisi ti o so nipa Gbigba Aawe ni ori Irinajo ninu tira Umdatul Ahkaam
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Alaye lori Awon Hadiisi ti o so nipa Gbigba Aawe ni ori Irinajo ninu tira Umdatul AhkaamBy Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
Esin Islam ati Oro nipa OseluBy Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
A
Alaye Hadiisi ti o so nipa Sakaatu Fitri ninu tira Umdatul Ahkaam


1
Alaye Hadiisi ti o so nipa Sakaatu Fitri ninu tira Umdatul Ahkaam
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Alaye Hadiisi ti o so nipa Sakaatu Fitri ninu tira Umdatul AhkaamBy Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
A
Alaye Itumo Awon Hadiisi ti o so nipa Irun Pipe ninu tira Umdatul Ahkaam


1
Alaye Itumo Awon Hadiisi ti o so nipa Irun Pipe ninu tira Umdatul Ahkaam
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Alaye Itumo Awon Hadiisi ti o so nipa Irun Pipe ninu tira Umdatul AhkaamBy Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
Alaye Lori bi Anabi se maa nse AluwalaBy Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro