1- Ninu abala yi ọrọ waye lori awọn nkan ti o ye ki arinrinajo se ki o to bẹrẹ irinajo rẹ. 2- Ninu abala yi ọrọ waye lẹkunrẹrẹ lori awọn ẹkọ ti o yẹ ki arinrinajo maa mu lo ni asiko ti ba nse irinajo rẹ.
Oro nipa awon ohun ti a maa nyo Saka ninu won, ati oundiwon ti a o yo ninu awon nkan ti Saka wo, Olubanisoro si bere pelu Aayah Alukuraani ti o nso nipa ijiya ti nbe fun awon ti won maa nko dukia jo laiyo Saka ninu re.
Idanileko yi so nipa awon idajo esin ti o ro mo irun pipe, oniwaasi so oro nipa re ni ifosiwewe nigbati o nse alaye awon hadiisi ti o ro mo o.
Idanileko yi so nipa awon eko ti Islam gbe kale fun eniti o ba ngba aawe gege bii yiyara fun isinu ati lilora lati je saari, bakannaa ni oludanileko tun so oro nipa asiko ti aawe maa nbere ati asiko ti o maa npari, o si tun so nipa bi esin Islam se se aawe agbayipo ni eewo.
1- Idanilẹkọ yi sọ nipa itumọ aladugbo pẹlu itọka rẹ lati inu Alukurani, bakannaa ọrọ tun waye lori diẹ ninu awọn iwọ aladugbo gẹgẹ bii ki Musulumi jẹ ki ọkan aladugbo rẹ balẹ, ki o ma je ki suta tabi aburu wa lati ọwọ rẹ si aladugbo rẹ. 2- Itẹsiwaju alaye lori awọn iwọ aladugbo, ọrọ waye nibẹ wipe ninu awọn iwọ aladugbo yoku ni: didaabobo o, sise daradara si i, sise amumọra fun aburu ọwọ rẹ ati bẹẹbẹẹ lọ.
Idanileko yi so nipa awon nkan wonyi:(1) Itumo Ayanmo. (2) Gbigba ayanmo ni ododo je okan ninu awon origun igbagbo. (3) Olohun ti O da awa eda ni O da awon ohun ti a n se ni ise. (4) Awon ipele Ayanmo. (5) Ninu awon idi ti Olohun fi se Ayanmo ni ohun asiri ati ipamo.
Eyi ni alaye awon Hadisi ti o n so nipa awon ojo ti Shari’ah ko fun Musulumi lati maa gba aawe ninu won ati awon eko esin ti o ro mo won.
Alaye ohun ti o se okunfa ogun yii ati awon isele ti o waye nibi sise ipalemo fun ogun naa eyi ti o je eri ododo lori wipe Annabi Muhammad ojise Olohun ni. Alaye si tun waye lori aranse ti Olohun se fun ojise Re ninu ogun naa.
Idanileko yi je alaye lori hadiisi eleekeje ninu tira “Umdatul Ahkaam”, koko oro idanileko naa ni alaye nipa bi ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o o maa ba a- se maa nse aluwala.
Daily Yoruba radio programs from Adventist World Radio
Alaye nipa ipo Saka yiyọ ninu ẹsin Islam ati awọn anfaani ti o wa nibi yiyọ rẹ yala ni abala ẹsin ni tabi abala iwa.
1- Alaye ni ekunrere lori eto ise egbe alajeseku ni ilana ti Islam, ati alaye nipa aburu ti o nbe nibi owo-ele (Riba), eri re lati inu Alukuraani mimo ati Oro Ojise Olohun. 2-Alaye ni afikun lori awon okowo ti Islam gbe kale ti a le maa lo ninu egbe alajeseku gege bii: Musharakah, Mudarabah, Murabahah ati bee bee lo.
1- Eleyi ni iforowero laarin Ijo Ahmadiyyah ati Ijo Tadomun Muslimeen lori wipe se Annabi Isa- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ku si ori igi agbelebu ni tabi ko ku, se won gbe gun Sanmo lo ni tabi o wa ni ibikan lori ile aye yii. 2- Eleyi ni itesiwaju iforowero laarin igun mejeeji pelu awon eri olukuluku won lati le fi oro won mule.
Idanil?k? yi s? nipa itum? biba aw?n keferi kopa ninu ?dun w?n p?lu aw?n ?ri lorisirisi lori bi biba aw?n keferi kopa ninu ?dun w?n se j? eew? fun Musulumi.
1- Ninu abala yi ọrọ waye lori wipe ounjẹ ti Ọlọhun Allah pese fun wa idẹra ni o jẹ ati alaye idi ti o fi jẹ idẹra. Bakannaa awọn nkan ti o dara pupọ lati se akiyesi rẹ nigba ti a ba fẹ jẹ ounjẹ. 2- Abala yii jẹ itẹsiwaju alaye lori awọn ẹkọ ti o rọ mọ jijẹ ati mimu, ẹkunrẹrẹ alaye si waye lori awọn nkan ti o dara pupọ lati jina si ni asiko ti a ba fẹ jẹ tabi mu.
Ibanisoro yi da lori oro nipa adiokan Imam Abu Haniifa, biotile je wipe olubanisoro menu ba adiokan awon Imaamu mereerin. Ohun ti o si se okunfa eleyi ni bi apa kan ninu awon alaimokan ni awujo se npe Imaam Abu Haniifa ni keeferi nitori awon iruju kan ti o nbe fun won nipa adiokan re. Eleyi ni oniwaasi yi se alaye re ni ekunrere, ki Olohun fi se awon Musulumi ni anfaani.
1- Alaye lori Irun Ọdun mejeeji ati awọn ofin ti o rọ mọ aaye ikirun pẹlu awọn imura ti wọn fẹ ki a mu fun Irun ọdun. 3- Idanileko ni apa yi da lori awọn ẹwa khutuba Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ni ọjọ odun ati tita koko ọrọ lori wipe se o maa ngbe minbari lọ si aaye ikirun ni tabi wọn mọ pa si ibẹ.
Alaye nipa imora oniyagbe (imora ti kosi omi nibe) ati awon idajo esin ti o so mo o.
Alaye ni ekunrere wa ninu ibanisoro yi lori awon nkan ti o leto fun Musulumi lati maa lo fun idena arun ati lati wa iwosan nigbati arun ba n se e. Bakannaa ni oro tun waye lori awon oogun ti o leto fun Musulumi lati lo ti o si so awon nkan ti esin se ni eewo fun Musumi.
Idanil?k? nipa aw?n ohun eew? ti o ti di gbajum? ni awuj? wa ni ode oni p?lu ?ri ikil? aw?n iwa ibaj? yii lati inu Alukuraani ati Sunnah Anabi.
Eleyi ni itumo awon hadiisi kan ti o so nipa sakaatul fitri ti awon Yoruba npe ni jaka. Oniwaasi se alaye awon idajo esin ti o ro mo o gege bii awon ti o ye ki o yo o, irufe ounje ti a fi maa nyo o ati odiwon ti o ye ki a yo.
Diẹ ninu awọn okunfa ipanle, janduku ati aigbọran ti awọn ọmọ ya kalẹ si awujọ. Itẹsiwaju ninu alaye awọn okunfa ipanle pẹlu awọn ọna abayọ si awọn iwa buburu yii.
1- Idanilẹkọ ni agbegbe yii sọ awọn ayọka Alukuraani ati ẹgbawa hadisi ti nse apejuwe bi Ina se ri. 2- Alaye awọn okunfa ti o maa nmu eniyan wọ Ina, awọn okunfa yii pin si meji: (1) Okunfa ti o maa nmu eniyan bẹ ninu Ina lọ gbere, (2) okunfa ti o maa nmu Musulumi bẹ ninu Ina fun igba diẹ.
1- Ibanisoro yii se afihan orisi ona meta ti Okan pin si, bee si ni Olubanisoro je ki a mo awon orisi arun ti o ma nse Okan. 2- Alaye ni afikun lori okan ti o nse aare ati ohun ti o je iwosan fun un. Iwosan ti o si dara julo ni nini igbagbo ti o peye ninu Olohun Allah ati mima ka Alukurani Alaponle ni gbogbo igba.
Pataki irun kiki ati wipe ohun ni ak?k? ohun ti Musulumi yoo se isiro r? ni ?j? ajinde.Di? ninu aw?n aisedeede naa g?g? bii: aifarabal?, wiwo ?tun wosi lori irun ati b??b?? l?.
1- Se awa Musulumi ni eto Kankan lori ile Filistin? Kinni awon igbiyanju ti awon asaaju Musulumi ti se ninu itan lori ile Filistin? Nje awa Musulumi aye ode oni ni igbiyanju kan lati se bi lori ati so ile Filistin di ile ominira fun Musulumi papaajulo masalaasi Kudusi? Gbogbo awon ibeere wonyi ni a o ri idahun fun ninu ibanisoro yi.2- Apa keji ibanisoro yi so nipa awon ogbon arekereke ti awon Yahudi lo lati fi gba ile Filistin ti won si le awon ti won ni ile kuro, bakannaa ni oro waye lori i ...
Idanil?k? yii da lori aw?n koko w?nyii:(i) Iha ti ?sin ko si Rukiya, Oogun if? ati Gbekude lilo,(ii) Idaj? aw?n nkan m?t??ta yii,(iii) Maj?mu Rukiya,(iv) Idaj? wiwe ayah Alukuraani ati dide m? ?run,(v) Di? ninu aw?n Rukiya ti a le fi se is? fun alaar?, ?m?de ati lati fi wa iwosan.
A platform for storytelling in the original languages
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
OHUN TI A LEE SE NIGBA TI AWON TI O YIWA KA KO BA RI RERE NINU AYE WA; ILE TI NSAISAN
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
NIPA IRANLOWO OLORUN, A GBODO MAA RO RERE NIPA ARA WA; ESE LO NMUN ILE SAISANBy Adventist World Radio
AWON ERE IGBORAN NI A RI NINU DEUTERONOMI 28By Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
MASE FI OJU TEMBELU ARA RE; GBENDEKE TI KRISTI
29:00
29:00
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
29:00
O LEE LU ALUYO NITORIPE O NI OLORUN NLA; GBENDEKE KRISTI NI IWA REBy Adventist World Radio
MASE YO ARA RE KURO ARA AWON TI WON LEE SE ASEYORI; IPENIJA WO LO DABI OKE EVERESTI NIWAJU RE, OLORUN A MUN E BORI REBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
MASE WA OHUN ABURU NIKAN NINU AYE ELOMIRAN; OFIN AABO LORI EMI ATI DUKIA
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
LATI LEE RI OHUN TI O DARA NINU AYE ELOMIRAN, A KO GBODO MAA WO ALEEBU WON; TI O NBA NLO OOGUN OLORO TABI O NJA, APANIYAN NI OBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
KINNI OHUN TI O NRI NINU AYE ELOMIRAN; OFIN IBOWOFUN
29:00
29:00
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
29:00
KO SI ENIKENI TI KO NI OHUN TI O DARA NINU AYE RE; IFE GBODO MUN GBOGBO MOLEBI BOWO FUN ARA WONBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
EBUN TI O DARA JU LATI FUN ENIKEJI; KINNI O RI?
28:45
28:45
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:45
EBUN TI O DARA JU LATI FUN ENIKEJI NI LATI RI ATI LATI MON RIRI OHUN RERE NINU AYE ELOMIRAN; SATIDE NI OJO ISINMIBy Adventist World Radio
OLORUN TI GBA WA LA,, O SI FE KI A BOWO FUN OFIN OHUNBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
OHUN TI ENIYAN NILO JU NI IFE; OFIN OLORUN 2
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
KO SI OHUN GIDI KAN TI A MAA PADANU TI A BA NFI IFE HAN SI ELOMIRAN; OFIN OLORUN GBODO FI ARA HAN NINU OHUN GBOGBO TI A NSEBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
IFE A MAA MUN IDARIJI ATI IWOSAN WA; OFIN OLORUN
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
ISOORE JE IFE TI O NSISE LOWO-LOWO; OLORUN FE KI A PA OFIN OUN MON TORI OHUN NI OLUGBALA WABy Adventist World Radio
A KO TII BERE IGBE AYE, AFI IGBA TI A BA NFI IFE HAN; AAWE TOOTO NII SE PELU SISE REREBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
OLORUN LO NRAN WA LOWO LATI FI IFE HAN; ONJE ORUN
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
NIBI TI IFE BA WA, KO NI SI A NTA KANGBAN, IPANIYAN ATI BEEBEE LO; BI OLORUN SE BO ELIJAH, O LEE BO AWA NAABy Adventist World Radio
IFE LA FI NSEGUN IKORIRA A SI MAA MUN ALAAFIA WA; OLORUN YOO MUN OHUN IKOKO GBOGBO WA SI GBANGBABy Adventist World Radio
IFE A MAA MUN ILERA WA; NIPA EMI OLORUN, OKE ISORO WA LE DI PETELEBy Adventist World Radio
DAN ORUKO JESU WO, KII KUNABy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
MASE FI ARA RE WE ELOMIRAN - 6; AYE ERANKO
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
TITI LAI NI A O MAA RI ENI TI O JU WA LO; TI O BA NDESE, O NGBE IGBE AYE ERANKOBy Adventist World Radio
OHUN TI OWO RE O TO, MA FI GOGO FAA; ESO TI EMI NI EROJA MESAN TI ONIGBAGBO KOOKAN GBODO NIBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
MASE FI ARA RE WEELOMIRAN - 4; EJE TI NKE RARA
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
MASE JU ARA RE LO; TI A BA DA ESE NIKOKO, OLORUN NWO WABy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
MASE FI ARA RE WE ELOMIRAN - 3; IRU OMO TAANI IWO NSE?
29:00
29:00
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
29:00
O MAA BO TALENTI RE MOLE NIGBA TI O BA NFI ARA RE WE ELOMIRAN; JESU TI RA WA PADA KURO NI IKU AYERAYEBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
MASE FI ARA RE WE ELOMIRAN 2; AWORAN OLORUN
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
FOJUSUN IBI TI OLORUN TI FUN E NI ASEYORI, KI O SI MAA DUPE ; GEGEBI AWORAN OLORUN, A GBODO MAA HUWA BII ELEDA WABy Adventist World Radio
OLORUN TI LANA ASEYORI SILE FUN ENIKOOKAN WA, NITORINAA A KO GBODO SE AFARAWE ELOMIRAN; A GBODO JE KI OHUN TI OLORUN FI FUN WA TE WA LORUNBy Adventist World Radio
JESU NI OLORUN TI YAN GEGEBI JESU, ONIDAJO AGBAYEBy Adventist World Radio
TI A BA NSO ESO EMI, IWA WA YOO WU AWON ENIYAN; JESU BI OMO OLORUN TUN SISE BI OJISE OLORUN FUN IGBALA WABy Adventist World Radio
LATI MAA RIN NIPA TI EMIN TUMON SI PE EMIN OLORUN NDARI OHUN GBOGBO TI A NSE; DURO, KI O WO JESU FUN IGBALA ATI OJUTU SI ISORO REBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
OTITO TI KO FARASIN - KU NI OJOOJUMO; OLORUN ALAGBARA
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
ONIGBAGBO NILO LATI DI OKU SI NKAN TI ARA; BIBELI FIDI RE MUNLE PE JESU JE OLORUN ALAGBARABy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
SISE NI PIPE; OKUNRIN NAA T A NPE NI JESU
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
LATI SO ESO EMI, A NILO LATI MAA FI ARA WA FUN KRISTI NI OJOOJUMO; JESU WA SI AYE GEGEBI ENIYAN, O LA ISORO KOJA LATI GBA WA LABy Adventist World Radio
OLORUN NI O NFI ESO TI EMI FUN WA; ORUKO JESU NRAN WA LOWO LATI BORI ESUBy Adventist World Radio
A NILO LATI FI IGBE-AYE IGBAGBO WA HAN NIPA IGBE AYE WA; JESU KRISTI NILO LATI DI ARA KI O LE MON OHUN TI A NLA KOJA KI O SI LE GBA WABy Adventist World Radio
JESU ODO-AGUTAN OLORUN KO ESE WA LO. E JE KI A WOO KI A LE YEBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
IGBORAN SI OLORUN A MAA BUKUN FUN WA; JESU MESSIAH ARAYE
29:00
29:00
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
29:00
LATI LEE GBE IGBE AYE IGBAGBO, A GBODO SE AAPON LATI MUN IGBAGBO WA DAGBA NI KORO; JESU GEGEBI MESSIAH TI GBA AMIN ORORO LATI GBA ARAYE LABy Adventist World Radio
NIGBA TI A BA SE IGBORAN SI OFIN OLORUN, A NLANA FUN OLORUN LATI BUKUN WA; OLORUN WA PELU WA NINU IPONJU WABy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
IGBORAN TI O NWO NI SAN; KRISTI, OMO OLORU
29:00
29:00
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
29:00
IGBORAN JE IFIHAN IFE WA TOOTO SI JESU; TI A BA NRIN PELU KRISTI, A O RI ISE IYANU RE TI YOO JE KI A LEE SO WIPE KRISTI JE OMO OLORUNBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
AWON IWA OMO OLORUN TOOTO; EMMANUELI WA LAAYE
28:58
28:58
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:58
1KORINTI 6:1-10 E JE KI A GBA KI WON YAN WA JE; NIPASE JESU, A NI ANFAANI LATI BAWA LAJA PELU OLORUNBy Adventist World Radio
A KO LE SE ALABAPIN IFE KRISTI PELU AWON ELOMIRAN TI AWA FUNRAWA O BA TII NI IRIRI RE; JESU KRISTI NI ORO OLORUN NIPA RE NI OLORUN DA AYEBy Adventist World Radio
IGBE-AYE AISODODO JE IKUNA NIPA TI EMI; JESU TI WA LATI IBERE-PEPE; O SI JE OLUGBALA ARAYEBy Adventist World Radio
IKU NI OTA IKEHIN TI KRISTI YOO PARUN, A GBOD FI AYE FUN KRISTI KI A MA BAA PAWA RUN PELU REBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
MUNRA BI O SE FE KI AWON EEYAN BA O SORO; KINNI EMI RE?
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
A MAA NFE MON OHUN TI O WA NINU IPAMO, NITORI NAA, DASO BO IHOOHO RE; OLORUN NI O NI EMI WABy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
MA JE KI IRIRI ATEYINWA JA O KULE; LILO KURO LODO OLORUN
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
TI IJAKULE BA DE, KI A PADA SIBI AGBEKALE WA, KI A SI TE'SIWAJU; OHUNKOHUN TI IBAA DE BA WA, A KO GBODO JOWO OLORUN SÍLEBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
KINNI ISESI RE NIGBA IJAKULE; AWON OHUN IKOSE
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
A GBODO RI IJAKULE GEGEBI ANFAANI LATI NI IBERE OTUN; BI OHUN IKOSE TILE WA, A KO GBODO GBA WON LAAYE LATI DA OKAN WA RUBy Adventist World Radio
MAA BA AWON TI O FEE SE AWOKOSE WON D'ÓREBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
BA AWON TI WON LEE RAN E LOWO LATI SORIIRE SORE -; DI OWO RE MUN
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
TI A BA GBEKELE OLORUN, YIO DARI WA SI AWON TI YOO RAN WA LOWO LATI SE ASEYORI; TI A BA DI OWO ELEDA WA MUN, YO MUN WA LA IRUMI AYE YII JABy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
BAWO NI A SE LE SE ASEYORI NI AYE WA; ASE IGBEYAWO
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
MAA BA AWON ALASEYORI DORE TI O BA FEE SE ASEYORI. KI A DE KUN FUN ADURA; TI A BA FEE KOPA NIBI IGBEYAWO ODO AGUTAN, A GBODO FI AYE WA FUN KRISTIBy Adventist World Radio
JESU NI AJARA TOOTO, TI A BA YA ARA WA KURO, A O GBE DANUBy Adventist World Radio
FI IFE DIPO IKORIRA; IFE AYERAYE TI OLORUN NI LO JE KI O FI OMO RE KAN SOSO FUN WABy Adventist World Radio
FI IFE HAN NI IGBA GBOGBO; AWON OLODODO A MAA SO ESO IWA MIMOBy Adventist World Radio
KI A FI MAJELE IFE FUN AWON OLOLUFE WA; E JE KI A GBE AYE WA BI ENI TI O NRETI IYE AYERAYEBy Adventist World Radio
MAJELE IFE KII PO JU; A LEE SE ORIIRE NLA NINU KRISTIBy Adventist World Radio
IFE JE MAJELE TI O DARA; ORUKO JESU LAGBARABy Adventist World Radio
MAJELE KAN WA TI O DARA; A O GBA ERE ISE WABy Adventist World Radio
AABO WA FUN OJO OLA RE NINU OLORUNBy Adventist World Radio