Ohun Aanu is a powerful Yoruba podcast.
Idanil?k? nipa aw?n ohun eew? ti o ti di gbajum? ni awuj? wa ni ode oni p?lu ?ri ikil? aw?n iwa ibaj? yii lati inu Alukuraani ati Sunnah Anabi.
Alaye ohun ti a n pe ni igberaga ohun naa ni ki eniyan maa se atako ododo ti o fi oju han ati yiyepere awon eniyan miran.
1- Se awa Musulumi ni eto Kankan lori ile Filistin? Kinni awon igbiyanju ti awon asaaju Musulumi ti se ninu itan lori ile Filistin? Nje awa Musulumi aye ode oni ni igbiyanju kan lati se bi lori ati so ile Filistin di ile ominira fun Musulumi papaajulo masalaasi Kudusi? Gbogbo awon ibeere wonyi ni a o ri idahun fun ninu ibanisoro yi.2- Apa keji ibanisoro yi so nipa awon ogbon arekereke ti awon Yahudi lo lati fi gba ile Filistin ti won si le awon ti won ni ile kuro, bakannaa ni oro waye lori i ...
Oro nipa awon ohun ti a maa nyo Saka ninu won, ati oundiwon ti a o yo ninu awon nkan ti Saka wo, Olubanisoro si bere pelu Aayah Alukuraani ti o nso nipa ijiya ti nbe fun awon ti won maa nko dukia jo laiyo Saka ninu re.
Daily Yoruba radio programs from Adventist World Radio
1- Ibanisoro yii se afihan orisi ona meta ti Okan pin si, bee si ni Olubanisoro je ki a mo awon orisi arun ti o ma nse Okan. 2- Alaye ni afikun lori okan ti o nse aare ati ohun ti o je iwosan fun un. Iwosan ti o si dara julo ni nini igbagbo ti o peye ninu Olohun Allah ati mima ka Alukurani Alaponle ni gbogbo igba.
Diẹ ninu awọn okunfa ipanle, janduku ati aigbọran ti awọn ọmọ ya kalẹ si awujọ. Itẹsiwaju ninu alaye awọn okunfa ipanle pẹlu awọn ọna abayọ si awọn iwa buburu yii.
Ibanisoro yi da lori oro nipa adiokan Imam Abu Haniifa, biotile je wipe olubanisoro menu ba adiokan awon Imaamu mereerin. Ohun ti o si se okunfa eleyi ni bi apa kan ninu awon alaimokan ni awujo se npe Imaam Abu Haniifa ni keeferi nitori awon iruju kan ti o nbe fun won nipa adiokan re. Eleyi ni oniwaasi yi se alaye re ni ekunrere, ki Olohun fi se awon Musulumi ni anfaani.
1- Idanilẹkọ ni agbegbe yii sọ awọn ayọka Alukuraani ati ẹgbawa hadisi ti nse apejuwe bi Ina se ri. 2- Alaye awọn okunfa ti o maa nmu eniyan wọ Ina, awọn okunfa yii pin si meji: (1) Okunfa ti o maa nmu eniyan bẹ ninu Ina lọ gbere, (2) okunfa ti o maa nmu Musulumi bẹ ninu Ina fun igba diẹ.
Pataki irun kiki ati wipe ohun ni ak?k? ohun ti Musulumi yoo se isiro r? ni ?j? ajinde.Di? ninu aw?n aisedeede naa g?g? bii: aifarabal?, wiwo ?tun wosi lori irun ati b??b?? l?.
Idanileko yi so nipa awon nkan wonyi:(1) Itumo Ayanmo. (2) Gbigba ayanmo ni ododo je okan ninu awon origun igbagbo. (3) Olohun ti O da awa eda ni O da awon ohun ti a n se ni ise. (4) Awon ipele Ayanmo. (5) Ninu awon idi ti Olohun fi se Ayanmo ni ohun asiri ati ipamo.
Alaye ohun ti o se okunfa ogun yii ati awon isele ti o waye nibi sise ipalemo fun ogun naa eyi ti o je eri ododo lori wipe Annabi Muhammad ojise Olohun ni. Alaye si tun waye lori aranse ti Olohun se fun ojise Re ninu ogun naa.
In Africa, indigenous names or surnames are richly labored with meaning, identity, origin and stories that are passed on from one generation to the next. In celebration of African identity and indigenous or mother tongue languages, Tinzwe Media is proud to launch its latest offering – Inside Wants Out – an African mother tongue poetry podcast. The project is powered by the South African Department of Sports, Arts and Culture (DSAC) and the theme for season one of the podcast is 'African Poet ...
JESU NFUN WA NI IGBOYA LATI LEE SE OHUN GBOGBOBy Adventist World Radio
ISE ASEKARA LATI FIHAN PE A JE OMO-ODO RERE; TI A BA KA ORO OLORUN TI A SI GBORAN, A LEE NI OGBO LATI ORUN WABy Adventist World Radio
WIWA OWO AWAJU; JESU, OLUSO-AGUTAN WA; OLE NI SATANI NIGBATI JESU JE OLUSO-AGUTAN WABy Adventist World Radio
OWO GBOGBO EEYAN LO DI; LO SI ODO KRISTI ONISEGUN NLA NI FUN IWOSANBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
ADINA GBOOKU FUN ISOKAN IDILE; JESU, OLUWA AGBAYE
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
KI A MA RAYE FUN IDILE; GBA JESU BI OLUGBALA AYE REBy Adventist World Radio
JAGIDI-JAGAN A MAA FA IYAPA NINU IDILE; JESU NI AKASO SI ODO OLORUNBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
IDENA FUN IDILE ALAAFIA; KRISTI, IREKOJA WA
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
JAGIDI-JAGAN, OOGUN OLORO ATI BEE BEE LO LEE SE IDENA FUN ISOKAN IDILE; TI A BA GBA JESU NI OLUWA WA, OLORUN YOO DARI EJE WABy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
IDENA FUN ISOKAN IDILE; JESU, OLU ALUFA WA
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
OLORUN NI O GBE IDILE KALE; JESU YE BI OLUSO-AGUTAN WA NITORI OUN ODO AGUTAN TI KO NI ABAWONBy Adventist World Radio
IDARIJI NFUN NI AYOBy Adventist World Radio
MAA SAAPON BEENI KI O MASE GBA ONA ALUMONKOROYIN LATI SE ASEYORI; BINU, MASI SE SEBy Adventist World Radio
IDARIJI NMUN ASEYORI WABy Adventist World Radio
LATI SE ASEYORI MAA SE AAPON LATI DAGBA SOKE; STEFANU DARIJI AWON TI O PAABy Adventist World Radio
MASE FI ONI DONI', FOLA DOLA; DARIJI LATI BORI OGUN AYEBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
ASEYORI BERE LATI OOKAN AYA WA; DARIJI KI O LEE BORI IKU AYERAYE;
29:00
29:00
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
29:00
GBAGBO PE WAA SE ASEYORI PELU AGBARA OLORUN; KO SI IDARIJI NINU ISA OKUBy Adventist World Radio
OMINRAN WA NINU RE; DARAJI KI O LEE JOGUN AYERAYEBy Adventist World Radio
ELESE NI O, NITORI NAA RE ARA RE SILE DARIJI ELOMIRANBy Adventist World Radio
IBERU A MAA MUN KI ENIYAN MA LEE DEBI ASEYORI RE TABI KI O MAA SAISAN; NOAH MUN OTI YO, DIPO KI O SI DARIJI, O FI OMO RE REBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
OTA TI O BURU JU NI ARA ENI; JESU NDARIJI
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
GBADURA LATI BORI ERAN ARA; DARIJI BI JESU SE DARIJI OBINRIN TI A MUN NINU PANSAGABy Adventist World Radio
MASE DAAMUN OKAN RE NIPA AWON OTA RE NITORI O KO LEE MON WON TAN; IDI TI A FI GBODO DARIJI; ANOTHER REASON WHY YOU NEED TO FORGIVE IS TO SHOW HUMILITYIDI MIRAN TI A FI GBODO DARIJI NI LATI FI EMI IRELE HANBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
PATAKI NINI OTA - JOSEFU; JESU NI O NDARIJI
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
AWON EGBON JOSEFU ATI AYA POTIFERI TI WON JE OTA RE NI WON POLONGO RE; DARIJI, TI O BA FE KI OLORUN DARIJI OBy Adventist World Radio
NINI OTA FIHAN PE A NSE OHUN RERE; IDARIJI NMUN ITUSILE WABy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
AGBARA TI O WA NINU OTA ENI; DARIJI BI A TI SE DARIJI O
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
A NILO ATI ORE ATI OTA LATI SE ASEYORI; OMO-ODO BUBURU NI KO LEE DARIJIBy Adventist World Radio
IDARIJI A MAA FA ITUSILEBy Adventist World Radio
LATI SE ASEYORI, A GBODO NI IGBOYA LATI SE OHUN RERE TI ENIKAN O SE RI; ENI TI O NDARIJI SE ARA RE NI OPOLOPO ANFAANIBy Adventist World Radio
LATI LEE SE ASEYORI, A GBODO MAA RO KI A SI GBADURA NIPA RE; AINIDARIJI JE ABAAWON NI AYE KRISTIANIBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
FI ARA RE JI FUN OLORUN; ONIGBAGBO GBODO MAA DARIJI ELOMIRAN
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
KI A TOO LEE MAA RO ERO RERE NIPA ARA WA, A GBODO JOWO ARA WA FUN OLORUN PATA-PATA; DARIJI ELOMIRAN TI O BA FE KI OLORUN DARIJI OBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
YI ERO INU RE NIPA ARA RE PADA; IDI TI A FI GBODO DARIJI ARA WA
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
IWOSO RE SO NIPA ERO RE NIPA ARA RE; IDARIJI A MAA BAWA SE OGUN AYE WABy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
MASE FI OJU TEMBELU ARA RE; KO SI IBI TI A LEE SA LO FUN IDARIJI
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
OLORUN DA WA DARA-DARA; IDARIJI JE ARA IGBE-AYE WA, NITORINAA A GBODO KO LATI DARIJIBy Adventist World Radio
A GBODO YI PADA KURO NI ONA BUBURU WA; TI A KO BA DARI JI ARA WA, A NILO ITUSILEBy Adventist World Radio
Topic: Amona nf’ona han Afoju Description: Matt 26:41 “Watch and pray, lest you enter into temptation. The spirit indeed is willing, but the flesh is weak.”By MercygateMedia
AWON ERE IGBORAN NI A RI NINU DEUTERONOMI 28By Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
MASE FI OJU TEMBELU ARA RE; GBENDEKE TI KRISTI
29:00
29:00
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
29:00
O LEE LU ALUYO NITORIPE O NI OLORUN NLA; GBENDEKE KRISTI NI IWA REBy Adventist World Radio
MASE YO ARA RE KURO ARA AWON TI WON LEE SE ASEYORI; IPENIJA WO LO DABI OKE EVERESTI NIWAJU RE, OLORUN A MUN E BORI REBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
OHUN TI A LEE SE NIGBA TI AWON TI O YIWA KA KO BA RI RERE NINU AYE WA; ILE TI NSAISAN
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
NIPA IRANLOWO OLORUN, A GBODO MAA RO RERE NIPA ARA WA; ESE LO NMUN ILE SAISANBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
MASE WA OHUN ABURU NIKAN NINU AYE ELOMIRAN; OFIN AABO LORI EMI ATI DUKIA
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
LATI LEE RI OHUN TI O DARA NINU AYE ELOMIRAN, A KO GBODO MAA WO ALEEBU WON; TI O NBA NLO OOGUN OLORO TABI O NJA, APANIYAN NI OBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
KINNI OHUN TI O NRI NINU AYE ELOMIRAN; OFIN IBOWOFUN
29:00
29:00
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
29:00
KO SI ENIKENI TI KO NI OHUN TI O DARA NINU AYE RE; IFE GBODO MUN GBOGBO MOLEBI BOWO FUN ARA WONBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
EBUN TI O DARA JU LATI FUN ENIKEJI; KINNI O RI?
28:45
28:45
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:45
EBUN TI O DARA JU LATI FUN ENIKEJI NI LATI RI ATI LATI MON RIRI OHUN RERE NINU AYE ELOMIRAN; SATIDE NI OJO ISINMIBy Adventist World Radio
OLORUN TI GBA WA LA,, O SI FE KI A BOWO FUN OFIN OHUNBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
OHUN TI ENIYAN NILO JU NI IFE; OFIN OLORUN 2
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
KO SI OHUN GIDI KAN TI A MAA PADANU TI A BA NFI IFE HAN SI ELOMIRAN; OFIN OLORUN GBODO FI ARA HAN NINU OHUN GBOGBO TI A NSEBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
IFE A MAA MUN IDARIJI ATI IWOSAN WA; OFIN OLORUN
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
ISOORE JE IFE TI O NSISE LOWO-LOWO; OLORUN FE KI A PA OFIN OUN MON TORI OHUN NI OLUGBALA WABy Adventist World Radio
A KO TII BERE IGBE AYE, AFI IGBA TI A BA NFI IFE HAN; AAWE TOOTO NII SE PELU SISE REREBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
OLORUN LO NRAN WA LOWO LATI FI IFE HAN; ONJE ORUN
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
NIBI TI IFE BA WA, KO NI SI A NTA KANGBAN, IPANIYAN ATI BEEBEE LO; BI OLORUN SE BO ELIJAH, O LEE BO AWA NAABy Adventist World Radio
IFE LA FI NSEGUN IKORIRA A SI MAA MUN ALAAFIA WA; OLORUN YOO MUN OHUN IKOKO GBOGBO WA SI GBANGBABy Adventist World Radio
IFE A MAA MUN ILERA WA; NIPA EMI OLORUN, OKE ISORO WA LE DI PETELEBy Adventist World Radio
DAN ORUKO JESU WO, KII KUNABy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
MASE FI ARA RE WE ELOMIRAN - 6; AYE ERANKO
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
TITI LAI NI A O MAA RI ENI TI O JU WA LO; TI O BA NDESE, O NGBE IGBE AYE ERANKOBy Adventist World Radio
OHUN TI OWO RE O TO, MA FI GOGO FAA; ESO TI EMI NI EROJA MESAN TI ONIGBAGBO KOOKAN GBODO NIBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
MASE FI ARA RE WEELOMIRAN - 4; EJE TI NKE RARA
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
MASE JU ARA RE LO; TI A BA DA ESE NIKOKO, OLORUN NWO WABy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
MASE FI ARA RE WE ELOMIRAN - 3; IRU OMO TAANI IWO NSE?
29:00
29:00
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
29:00
O MAA BO TALENTI RE MOLE NIGBA TI O BA NFI ARA RE WE ELOMIRAN; JESU TI RA WA PADA KURO NI IKU AYERAYEBy Adventist World Radio
A
AWR Yoruba / èdèe Yorùbá


1
MASE FI ARA RE WE ELOMIRAN 2; AWORAN OLORUN
28:59
28:59
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
28:59
FOJUSUN IBI TI OLORUN TI FUN E NI ASEYORI, KI O SI MAA DUPE ; GEGEBI AWORAN OLORUN, A GBODO MAA HUWA BII ELEDA WABy Adventist World Radio