Oniwaasi so wipe awon majemu meta kan wa fun jije eni Olohun (i) Ki eniyan so asepo laarin ara re ati Olohun re (ii) Ki o so asepo laarin oun ati emi ara re (iii) Ki o so asepo laarin oun ati awujo re.
Oro lori bi Annabi- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- se ko awon Sahabe re ni eko ti aye won fi dara ti orun won naa si rorun.
Idanileko yi je alaye lori hadiisi eleekeje ninu tira “Umdatul Ahkaam”, koko oro idanileko naa ni alaye nipa bi ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o o maa ba a- se maa nse aluwala.
Idanileko yi so nipa awon nkan wonyi:(1) Itumo Ayanmo. (2) Gbigba ayanmo ni ododo je okan ninu awon origun igbagbo. (3) Olohun ti O da awa eda ni O da awon ohun ti a n se ni ise. (4) Awon ipele Ayanmo. (5) Ninu awon idi ti Olohun fi se Ayanmo ni ohun asiri ati ipamo.
1- Alaye ni ekunrere lori eto ise egbe alajeseku ni ilana ti Islam, ati alaye nipa aburu ti o nbe nibi owo-ele (Riba), eri re lati inu Alukuraani mimo ati Oro Ojise Olohun. 2-Alaye ni afikun lori awon okowo ti Islam gbe kale ti a le maa lo ninu egbe alajeseku gege bii: Musharakah, Mudarabah, Murabahah ati bee bee lo.
Ibanisoro yi da lori oro nipa adiokan Imam Abu Haniifa, biotile je wipe olubanisoro menu ba adiokan awon Imaamu mereerin. Ohun ti o si se okunfa eleyi ni bi apa kan ninu awon alaimokan ni awujo se npe Imaam Abu Haniifa ni keeferi nitori awon iruju kan ti o nbe fun won nipa adiokan re. Eleyi ni oniwaasi yi se alaye re ni ekunrere, ki Olohun fi se awon Musulumi ni anfaani.
Alaye ohun ti o se okunfa ogun yii ati awon isele ti o waye nibi sise ipalemo fun ogun naa eyi ti o je eri ododo lori wipe Annabi Muhammad ojise Olohun ni. Alaye si tun waye lori aranse ti Olohun se fun ojise Re ninu ogun naa.
1- Alaye lori Irun Ọdun mejeeji ati awọn ofin ti o rọ mọ aaye ikirun pẹlu awọn imura ti wọn fẹ ki a mu fun Irun ọdun. 3- Idanileko ni apa yi da lori awọn ẹwa khutuba Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ni ọjọ odun ati tita koko ọrọ lori wipe se o maa ngbe minbari lọ si aaye ikirun ni tabi wọn mọ pa si ibẹ.
Eyi ni ?kunr?r? alaye lori bi Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- se maa n ki Irun It?r? Ojo p?lu sise afihan aw?n orisirisi ?na ti o gba se adua lati t?r? ojo nigba aye r?.
1- Ibanisoro yii se afihan orisi ona meta ti Okan pin si, bee si ni Olubanisoro je ki a mo awon orisi arun ti o ma nse Okan. 2- Alaye ni afikun lori okan ti o nse aare ati ohun ti o je iwosan fun un. Iwosan ti o si dara julo ni nini igbagbo ti o peye ninu Olohun Allah ati mima ka Alukurani Alaponle ni gbogbo igba.
1- Eleyi ni iforowero laarin Ijo Ahmadiyyah ati Ijo Tadomun Muslimeen lori wipe se Annabi Isa- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ku si ori igi agbelebu ni tabi ko ku, se won gbe gun Sanmo lo ni tabi o wa ni ibikan lori ile aye yii. 2- Eleyi ni itesiwaju iforowero laarin igun mejeeji pelu awon eri olukuluku won lati le fi oro won mule.
Iyapa Olohun Allah ati owo ele ni okunfa meji ti o lagbara julo fun isubu oro-aje, imoran si tun waye lori awon ona abayo si isoro yii.
Alaye nipa ola ti o nbe fun irun pipe ati awon idajo esin ti o ro m o o, olubanisoro se alaye wipe Ojise Olohun – ike ati ola Olohun ki o maa ba a- kii pe irun tabi se ikaama fun irun odun mejeeji: odun itunu aawe ati odun ileya.
A
Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam


1
Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam -1
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam -1By Sharafuddeen Gbadebọ Raji
A
Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam


1
Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam -3
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam -3By Sharafuddeen Gbadebọ Raji
I
Idajọ Irun ti a fi n wa Ojo (Sọlaatul-istiskaai)


1
Idajọ Irun ti a fi n wa Ojo (Sọlaatul-istiskaai)
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Idaj? Irun ti a fi n wa Ojo (S?laatul-istiskaai)By Sharafuddeen Gbadebọ Raji
O
Ola ti o wa fun Irun Pipe ati Awon Idajo Esin ti o sopo mo o


1
Ola ti o wa fun Irun Pipe ati Awon Idajo Esin ti o sopo mo o
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Ola ti o wa fun Irun Pipe ati Awon Idajo Esin ti o sopo mo oBy Sharafuddeen Gbadebọ Raji
A
Awon Alaye Esin Nipa Igbagbo si Ayanmon (Kadara)


1
Awon Alaye Esin Nipa Igbagbo si Ayanmon (Kadara)
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Awon Alaye Esin Nipa Igbagbo si Ayanmon (Kadara)By Abdul-jeleel Alagufon
Awon Eko Pataki Nibi Ogun KhandakBy Isa Akindele Solahudeen
Awon Okunfa Isubu Oro-aje Orile-edeBy Isa Akindele Solahudeen
Awon Arun Okan - 1By Isa Akindele Solahudeen
Awon Arun Okan - 2By Isa Akindele Solahudeen
N
Ninu Awon Iruju Jamaa Ahmadiyya (Qoodiyaaniyyah)


1
Ninu Awon Iruju Jamaa Ahmadiyya (Qoodiyaaniyyah) - 1
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Ninu Awon Iruju Jamaa Ahmadiyya (Qoodiyaaniyyah) - 1
N
Ninu Awon Iruju Jamaa Ahmadiyya (Qoodiyaaniyyah)


1
Ninu Awon Iruju Jamaa Ahmadiyya (Qoodiyaaniyyah) - 2
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Ninu Awon Iruju Jamaa Ahmadiyya (Qoodiyaaniyyah) - 2
Awon Iroyin Jije Eni OlohunBy Abdul-jeleel Alagufon
E
Egbe Alajeseku Ninu Islam (Islamic Co-Operative)


1
Egbe Alajeseku Ninu Islam (Islamic Co-Operative) - 1
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Egbe Alajeseku Ninu Islam (Islamic Co-Operative) - 1By Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
E
Egbe Alajeseku Ninu Islam (Islamic Co-Operative)


1
Egbe Alajeseku Ninu Islam (Islamic Co-Operative) - 2
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Egbe Alajeseku Ninu Islam (Islamic Co-Operative) - 2By Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
B
Bi Ojise Olohun ti ko Awon Saabe re ni Eko


1
Bi Ojise Olohun ti ko Awon Saabe re ni Eko
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Bi Ojise Olohun ti ko Awon Saabe re ni EkoBy Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
Alaye Lori bi Anabi se maa nse AluwalaBy Abdur-razaq Abdul-majeed Alaro
A
Adiokan Awon Imaamu Mereerin ni odo Awon oni Sunna


1
Adiokan Awon Imaamu Mereerin ni odo Awon oni Sunna
51:08
51:08
Play later
Play later
Lists
Like
Liked
51:08
Adiokan Awon Imaamu Mereerin ni odo Awon oni SunnaBy Abdur-rahman Adunola Abdul-wahab