1- Idanilẹkọ yii sọ nipa oniranran apejuwe nipa ibugbe Alujannah gẹgẹ bi awọn apejuwe yii se wa lati inu Alukuraani ati Sunnah Ojisẹ Ọlọhun. 2- Alaye lori awọn isẹ ti o maa nse okunfa wiwọ Alujannah gẹgẹ bi Ọlọhun ti se se iroyin rẹ lati inu Alukuraani ati Sunna.
Iroyin Alujannah ati Aw?n Olugbe r? - 2By Abdur Rahman Muhammadul Awwal
Iroyin Alujannah ati Aw?n Olugbe r? - 1By Abdur Rahman Muhammadul Awwal